Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 2:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó sì wà níbẹ̀ títítí Hẹ́rọ́dù fi kú. Èyí jẹ́ ìmúṣẹ àṣọtẹ́lẹ̀ ohun tí Olúwa sọ láti ẹnu wòlíì pé: “Mo pe ọmọ mi jáde láti Éjíbítì wá.”

Ka pipe ipin Mátíù 2

Wo Mátíù 2:15 ni o tọ