Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 19:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dáhùn pé, “Lóòótọ́ ni mo wí fún yín pé, ‘Nígbà ìsọdọ̀tun ohun gbogbo, nígbà tí Ọmọ-Ènìyàn yóò jókòó lórí ìtẹ̀ tí ó lógo, dájúdájú, ẹ̀yin ọmọ-ẹ̀yìn mi yóò sì jókòó lórí ìtẹ́ méjìlá láti ṣe ìdájọ́ ẹ̀yà Ísírẹ́lì méjìlá.

Ka pipe ipin Mátíù 19

Wo Mátíù 19:28 ni o tọ