Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 19:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin náà béèrè pé, “Àwọn wo ni òfin wọ̀nyí?” Jésù dáhùn pé, “ ‘Má ṣe pànìyàn, má ṣe ṣe panṣágà, má ṣe jalè, má ṣe ìjẹ̀rìí èké,

Ka pipe ipin Mátíù 19

Wo Mátíù 19:18 ni o tọ