Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 18:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Pétérù wá sọ́dọ̀ Jésù, ó béèrè pé, “Olúwa, nígbà mélòó ni arákùnrin mi yóò ṣẹ̀ mi, tí èmi yóò sì dáríjì í? Tàbí ní ìgbà méje ni?”

Ka pipe ipin Mátíù 18

Wo Mátíù 18:21 ni o tọ