Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 18:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí arákùnrin rẹ bá ṣẹ̀ ọ́, lọ ní ìkọ̀kọ̀ kí o sì sọ ẹ̀bi rẹ̀ fún un. Bí ó bá gbọ̀ tìrẹ, ìwọ ti mú arákùnrin kan bọ̀ sí ipò.

Ka pipe ipin Mátíù 18

Wo Mátíù 18:15 ni o tọ