Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 18:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ rí i pé ẹ kò fi ojú bẹ́ńbẹ́lú ọ̀kan nínú àwọn kékeré wọ̀nyí. Lóòótọ́ ni mo wí fún yin pé, nígbà gbogbo ni àwọn áńgẹ́lì wọn ní ọ̀run ń láti lọ wo ojú Baba mi tí ń bẹ ní ọ̀run.

Ka pipe ipin Mátíù 18

Wo Mátíù 18:10 ni o tọ