Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 14:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó rí afẹ́fẹ́ líle, ẹ̀rù bà á, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í rì. Ó kígbe lóhùn rara pé, “Gbà mí, Olúwa.”

Ka pipe ipin Mátíù 14

Wo Mátíù 14:30 ni o tọ