Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 14:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo wọn sì jẹ àjẹyó. Lẹ́yìn náà àwọn ọmọ-ẹ̀yìn kó àjẹkù jọ, ó kún agbọ̀n méjìlá.

Ka pipe ipin Mátíù 14

Wo Mátíù 14:20 ni o tọ