Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 13:56-58 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

56. Àwọn arábìnrin rẹ̀ gbogbo ha kọ́ ni ó ń bá wa gbé níhìn-ín yìí, nígbà náà níbo ni ọkùnrin yìí ti rí àwọn nǹkan wọ̀nyí?”

57. Inú bí wọn sí i.Ṣùgbọ́n Jésù wí fún wọn pé, “Wòlíì a máa lọ́lá ní ibòmíràn, àfi ní ilé ara rẹ̀ àti ní ìlú ara rẹ̀ nìkan ni wòlíì kò ti lọ́lá.”

58. Nítorí náà kò se iṣẹ́ ìyanu kankan níbẹ̀, nítorí àìnígbàgbọ́ wọn.

Ka pipe ipin Mátíù 13