Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 13:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ní ọjọ́ kan náà, Jésù kúrò ní ilé, ó jókòó sí etí òkun.

2. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn péjọ sọ́dọ̀ rẹ̀, tó bẹ́ẹ̀ tí ó fi bọ́ sínú ọkọ̀-ojú omi, ó jókòó, gbogbo ènìyàn sì dúró létí òkun.

3. Nígbà náà ni ó fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ òwe bá wọn sọ̀rọ̀, wí pé: “Àgbẹ̀ kan jáde lọ gbin irúgbìn sínú oko rẹ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 13