Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 12:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọbabìnrin gúsù yóò sì dìde ní ọjọ́ ìdájọ́ sí ìran yìí yóò sì dá a lẹ́bi; nítorí tí ó wá láti ilẹ̀ ìkangun ayé láti gbọ́ ọ̀rọ̀ ọgbọ́n láti ẹnu Sólóḿonì. Ṣùgbọ́n báyìí ẹni tí ó pọ̀ jù Sólómónì ń bẹ níhìn-ín yìí.

Ka pipe ipin Mátíù 12

Wo Mátíù 12:42 ni o tọ