Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 11:28-30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

28. “Ẹ wá sọ́dọ̀ mi gbogbo ẹ̀yin tí ń ṣiṣẹ́ tí a sì di ẹrù wí wúwo lé lórí, èmi yóò sì fún yín ní ìsinmi.

29. Ẹ gbé àjàgà mi wọ̀. Ẹ kọ́ ẹ̀kọ́ lọ́dọ̀ mi nítorí onínútútù àti onírẹ̀lẹ̀ ọkàn ni èmi, ẹ̀yin yóò sì fi ìsinmi fún ọkàn yín.

30. Nítorí àjàgà mi rọrùn ẹrù mi sì fúyẹ́.”

Ka pipe ipin Mátíù 11