Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 11:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ ènìyàn wá bá a yín jẹun, ó sì bá yin mu, wọ́n wí pé, ọ̀jẹun àti ọ̀mùtì; ọ̀rẹ́ àwọn agbowó òde àti àwọn ẹlẹ́sẹ̀, ṣùgbọ́n a dá ọgbọ́n láre nípa ìṣe rẹ̀.”

Ka pipe ipin Mátíù 11

Wo Mátíù 11:19 ni o tọ