Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 11:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lóòótọ̀ ni mó wí fún yín, nínú àwọn tí a bí nínú obìnrin, kò sí ẹni tí ó tí í dìde tí ó ga ju Jòhánù onítẹ̀bọmi lọ, síbẹ̀ ẹni tí ó kéré jù ní ìjọba ọ̀run ni ó pọ̀ jù ú lọ.

Ka pipe ipin Mátíù 11

Wo Mátíù 11:11 ni o tọ