Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 1:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí Jósẹ́fù ọkọ rẹ̀ tí í ṣe olóòótọ́ ènìyàn kò fẹ́ dójú tì í ní gbangba, ó ní èrò láti kọ̀ ọ́ sílẹ̀ ní ìkọ̀kọ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 1

Wo Mátíù 1:19 ni o tọ