Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 1:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ìran Jésù Kírísítì, ẹni tí í ṣe ọmọ Dáfídì, ọmọ Ábúráhámù:

2. Ábúráhámù ni baba Ísáákì;Ísáákì ni baba Jákọ́bù;Jákọ́bù ni baba Júdà àti àwọn arákùnrin rẹ̀,

3. Júdà ni baba Pérésì àti Ṣérà,Támárì sì ni ìyá rẹ̀,Pérésì ni baba Ésírónù:Ésírónù ni baba Rámù;

4. Rámù ni baba Ámínádábù;Ámínádábù ni baba Náhísónì;Náhísónì ni baba Sálímónì;

Ka pipe ipin Mátíù 1