Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 7:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gíríkì ní obìnrin náà, Ṣíríàfonísíà ní orílẹ̀ èdè rẹ̀. Ó bẹ Jésù kí ó bá òun lé ẹ̀mí Èsù náà jáde lára ọmọbìnrin òun.

Ka pipe ipin Máàkù 7

Wo Máàkù 7:26 ni o tọ