Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 7:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdí ni wí pé, Ohunkóhun tí ó bá wọ inú láti ìta, kò wọ inú ọkàn rárá, ṣùgbọ́n ó kọjá sí ikùn.” (Nípa sísọ èyí, Jésù fi hàn pé gbogbo oúnjẹ jẹ́ “mímọ́.”)

Ka pipe ipin Máàkù 7

Wo Máàkù 7:19 ni o tọ