Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 6:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó rí i wí pé àwọ́n ọmọ-ẹyin wà nínú wàhálà púpọ̀ ní wíwa ọkọ̀ náà nítorí ti ìjì líle ṣe ọwọ́ òdì sí wọn, nígbà tí ó sì dì ìwọ̀n ìṣọ́ kẹrin òru, ó tọ̀ wọ́n wá, ó ń rìn lórí omi òkun, òun sì fẹ́ ré wọn kọjá,

Ka pipe ipin Máàkù 6

Wo Máàkù 6:48 ni o tọ