Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 5:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì bẹ̀ ẹ́ gidigidi pé, “Ọmọbìnrin mi wà lójú ikú, mo bẹ̀ ọ́, wá fi ọwọ́ rẹ lé e, kí ara rẹ̀ lè dá, kí ó sì yè.”

Ka pipe ipin Máàkù 5

Wo Máàkù 5:23 ni o tọ