Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 5:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn olùtọ́jú ẹran wọ̀nyí sì sá lọ sí àwọn ìlú ńlá àti ìlú kéékèèkéé, wọ́n sì ń tan ìròyìn náà ká bí wọ́n ti ń sáré. Àwọn ènìyàn sì tú jáde láti fojú gán-án-ní ohun náà tí ó sẹlẹ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 5

Wo Máàkù 5:14 ni o tọ