Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 4:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kìkì òwe ni Jésù fi ń kọ́ àwọn ènìyàn ní ẹ̀kọ́ ìta gbangba rẹ̀. Ṣùgbọ́n lẹ́yìn èyí, nígbà tí ó bá sì wà pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, òun a sì sọ ìtumọ̀ ohun gbogbo.

Ka pipe ipin Máàkù 4

Wo Máàkù 4:34 ni o tọ