Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó tílẹ̀ jẹ́ wí pé,“ ‘wọn yóò rí i, wọn yóò sì gbọ́, kì yóò yé wọn,bẹ́ẹ̀ ni wọn kì yóò sì yípadà sí Ọlọ́run.Tàbí kí a dárí ẹ̀ṣẹ̀ jì wọ́n!’ ”

Ka pipe ipin Máàkù 4

Wo Máàkù 4:12 ni o tọ