Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 3:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn olùkọ́ni-ni-òfin ṣọkàlẹ̀ wá láti Jérúsálẹ́mù, wọn sì wí pé, “Ó ni Béélísébúbù, olórí àwọn ẹ̀mí Èṣù, ni ó sì fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde!”

Ka pipe ipin Máàkù 3

Wo Máàkù 3:22 ni o tọ