Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 16:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àmì wọ̀nyí yóò sì máa bá àwọn tí ó gbàgbọ́ lọ. Ní orúkọ mi ni wọ́n yóò máa lé ẹ̀mí èsù jáde. Wọn yóò máa fi èdè titun sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 16

Wo Máàkù 16:17 ni o tọ