Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 14:61 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Jésù dákẹ́.Olórí àlùfáà tún bi í, lẹ́ẹ̀kan sí i, ò ní, “Ṣé ìwọ ni Kírísítì náà, Ọmọ Ọlọ́run?”

Ka pipe ipin Máàkù 14

Wo Máàkù 14:61 ni o tọ