Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 14:47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ọ̀kan nínú àwọn tí ó dúró idà rẹ̀ yọ, ó fi sá ọmọ-ọ̀dọ̀ olórí àlùfáà, ó sì ge etí rẹ̀ bọ́ sílẹ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 14

Wo Máàkù 14:47 ni o tọ