Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 14:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó sì ti ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, lójú ẹsẹ̀ náà ni Júdásì ọ̀kan nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn méjìlá dé pẹ̀lú. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ti idà àti kùmọ́ lọ́wọ́, àwọn olórí àlùfáà, àwọn olùkọ́ òfin àti àwọn àgbààgbà Júù ni ó rán wọn wa.

Ka pipe ipin Máàkù 14

Wo Máàkù 14:43 ni o tọ