Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 14:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wá nígbà kẹ́ta, ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ máa sùn kí ẹ sì máa sinmi ó tó bẹ́ẹ, wákàtí náà ti dé, wò ó, a fi Ọmọ Ènìyàn lé àwọn ẹlẹ́sẹ̀ lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Máàkù 14

Wo Máàkù 14:41 ni o tọ