Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 12:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kí ni ẹ rò pé baba olóko yóò ṣe nígbà tí ó bá gbọ́ ohun tí ó ṣélẹ́. Dájúdájú yóò pa àwọn ẹni ibi wọ̀nyí. Yóò sì gba àwọn olùtọ́jú mìíràn sínú oko rẹ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 12

Wo Máàkù 12:9 ni o tọ