Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 12:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tún rán ọmọ-ọ̀dọ̀ mìíràn sí wọn. Bí àwọn àgbẹ̀ tí tún rí ọmọ-ọ̀dọ̀ tí ó rán sí wọn; wọ́n lù ú. Àní, wọ́n tilẹ̀ dá ọgbẹ́ sí i lórí, wọn rán an lọ ni ìtìjú.

Ka pipe ipin Máàkù 12

Wo Máàkù 12:4 ni o tọ