Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 12:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lákókò ìkórè, ọkùnrin náà rán ọ̀kan nínú àwọn ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ̀ sí àwọn tí ń tọ́jú oko tí ó fi sílẹ̀, láti gba ìpín tirẹ̀ wá nínú ohun ọ̀gbìn oko náà.

Ka pipe ipin Máàkù 12

Wo Máàkù 12:2 ni o tọ