Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 12:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn Ṣadusí tún wá sọ́dọ̀ rẹ̀, àwọn wọ̀nyí kò gbàgbọ́ pé àjíǹde ń bẹ. Ìbéèrè wọn ni pé,

Ka pipe ipin Máàkù 12

Wo Máàkù 12:18 ni o tọ