Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 11:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n mú ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà tọ Jésù wá. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn sì bọ́ ẹ̀wù wọn, wọ́n sì tẹ́ ẹ sí ẹ̀yìn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà fún Jésù láti jókòó lórí rẹ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 11

Wo Máàkù 11:7 ni o tọ