Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 11:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó pàṣẹ fún wọn pé, “Ẹ lọ sí abúlé tó wà lọ́hùn-ún nì. Nígbà tí ẹ bá sì wọlé, ẹ̀yin yóò rí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tí a so mọ́lẹ̀ tí ẹnikẹ́ni kò ì tí i gùn rí. Ẹ tú u, kí ẹ sì mú wá síhìn-ín.

Ka pipe ipin Máàkù 11

Wo Máàkù 11:2 ni o tọ