Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 11:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wọ Jerúsálémù ó sì lọ sí inú tẹ́ḿpílì. Ó wo ohun gbogbo yíká fínnífínní. Ó sì kúrò níbẹ̀, nítorí pé ilẹ̀ ti sú. Ó padà lọ sí Bẹ́tanì pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ méjìlá.

Ka pipe ipin Máàkù 11

Wo Máàkù 11:11 ni o tọ