Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 10:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí a kì yóò fún padá ní ọgọọgọ́rùn-ún àwọn ilé, tàbí arákùnrin, tàbí arábìnrin, tàbí ìyá, tàbí ọmọ, tàbí àti ilẹ̀, tàbí bí inúnibini tilẹ̀ wà. Gbogbo nǹkan wọ̀nyí yóò jẹ́ tirẹ̀ ní ayé yìí àti pé ní ayé tó ń bọ̀ yóò ní ìyè àìnípẹ̀kun.

Ka pipe ipin Máàkù 10

Wo Máàkù 10:30 ni o tọ