Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà, Jésù kúrò ní Kapanámù. Ó gba gúsù wá sí agbègbè Jùdíà, títí dé ìlà oòrùn odò Jọ́dánì. Bí i ti àtẹ̀yìnwá, ọ̀pọ̀ ènìyàn ló tún wá sọ́dọ̀ rẹ̀. Ó sì kọ́ wọn pẹ̀lú bí i ìṣe rẹ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 10

Wo Máàkù 10:1 ni o tọ