Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 1:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tọ̀ ọ́ lọ, ó fà á lọ́wọ́, ó sì gbé e dìde; lójú kan náà ibà náà fi sílẹ̀, ó sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún wọn.

Ka pipe ipin Máàkù 1

Wo Máàkù 1:31 ni o tọ