Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 1:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnu sì ya àwọn ènìyàn, tó bẹ́ẹ̀ tí wọ́n fi ń sọ láàrin ara wọn ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀. Wọ́n béèrè pẹ̀lú ìgbóná ara, pé, “Kí ni èyí? Irú ẹ̀kọ́ titun wo ni èyí? Ó ń fi agbára pàṣẹ fún àwọn ẹ̀mí àìmọ́ pàápàá wọ́n sì gbọ́ tirẹ̀.”

Ka pipe ipin Máàkù 1

Wo Máàkù 1:27 ni o tọ