Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 9:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe bí ìwọ̀n ijọ́ mẹ́jọ lẹ́yìn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí, ó mú Pétérù àti Jòhánù àti Jákọ́bù, ó gun orí òkè lọ láti lọ gbàdúrà.

Ka pipe ipin Lúùkù 9

Wo Lúùkù 9:28 ni o tọ