Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 8:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kò sí ẹnikẹ́ni, nígbà tí ó bá tán fìtílà tan, tí yóò fi ohun èlò bò ó mọ́lẹ̀, tàbí tí yóò gbé e sábẹ́ àketè; bí kò ṣe kí ó gbé e ka orí ọ̀pá fìtílà, kí àwọn tí ń wọ ilé lè rí ìmọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Lúùkù 8

Wo Lúùkù 8:16 ni o tọ