Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 7:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì yípadà sí obìnrin náà, ó wí fún Símónì pé, “Wo obìnrin yìí? Èmi wọ ilé rẹ, ìwọ kò fi omi wẹ ẹṣẹ̀ fún mi: ṣùgbọ́n òun, omije rẹ̀ ni ó fi ń rọ̀jò sí mi lẹ́sẹ̀ irun orí ni ó fi n nù wọ́n nù.

Ka pipe ipin Lúùkù 7

Wo Lúùkù 7:44 ni o tọ