Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 6:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó jọ Ọkùnrin kan, tí ó kọ́ ilé, tí ó sì wa ilẹ̀ jìn, tí ó sì fi ìpìlẹ̀ sọlẹ̀ lórí àpáta, nígbà tí kíkún omi sì dé, ìgbì omi bì lu ilé náà, kò sì lè mì ín nítorí tí a fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ sọlẹ̀ lórí àpáta.

Ka pipe ipin Lúùkù 6

Wo Lúùkù 6:48 ni o tọ