Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 6:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúkúlùkù igi ni a ń fi èso rẹ̀ mọ̀ ọn; nítorí lórí ẹ̀gún òṣùṣú, ènìyàn kì í ká èṣo ọ̀pọ̀tọ́ bẹ́ẹ̀ ni lórí ẹ̀gún ọ̀gàn a kì í ká èṣo àjàrà.

Ka pipe ipin Lúùkù 6

Wo Lúùkù 6:44 ni o tọ