Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 6:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ fifún ni, a ó sì fifún yín; òṣùnwọ̀n dáradára, àkìmọ́lẹ̀, àti àmìpọ̀, àkúnwọ́sílẹ̀, ni a ó wọ̀n fún àyà yín: nítorí òṣùnwọ̀n náà tí ẹ̀yin fi wọ̀n, òun ni a ó padà fi wọ̀n fún yín.”

Ka pipe ipin Lúùkù 6

Wo Lúùkù 6:38 ni o tọ