Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 6:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹ̀yin bá wín fún ẹni tí ẹ̀yin ń reti láti rí gbà padà, ọpẹ́ kínni ẹ̀yin ní? Àwọn ‘ẹlẹ́sẹ̀’ pẹ̀lú ń yá ‘ẹlẹ́sẹ̀,’ kí wọn lè gba ìwọ̀n bẹ́ẹ̀ padà.

Ka pipe ipin Lúùkù 6

Wo Lúùkù 6:34 ni o tọ