Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 6:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì bá wọn sọ̀kalẹ̀, ó sì dúró ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, pẹ̀lú ọpọ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, àti ọ̀pọ̀ ìjọ ènìyàn, láti gbogbo Jùdéà, àti Jerúsálémù, àti agbègbè Tírè àti Ṣídónì, tí wọ́n wá láti gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀, àti láti gba ìmúláradá kúrò nínú àrùn wọn;

Ka pipe ipin Lúùkù 6

Wo Lúùkù 6:17 ni o tọ