Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 5:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì pa òwe yìí fún wọn wí pé: “Kò sí ẹni tó lè ya asọ tuntun kí ó sì rán mọ́, èyí tó ti gbó. Tí ó ba ṣe èyí, yóò ba asọ tuntun jẹ́, èyí tí ó tuntun náà kì yóò ṣe dógba pẹ̀lú èyí tí ó ti gbó.

Ka pipe ipin Lúùkù 5

Wo Lúùkù 5:36 ni o tọ