Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 5:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì dáhùn ó wí fún wọn pé, “Ǹjẹ́ ó seé se kí àwọn àlejò ọkọ ìyàwó máa gbàwẹ̀ nígbà tí ọkọ ìyàwó wà pẹ́lú wọn bí?

Ka pipe ipin Lúùkù 5

Wo Lúùkù 5:34 ni o tọ